Someone sent me these prayers. It's quite interesting because it is in yoruba language. It is called Adura opin odun in ABD....Y
Year ending prayers in Yoruba alphabets
Too bad if you can't read Yoruba!!!! Get an Aayan Ogbufo (interpreter) or google d meaning or get a Yoruba Lang dictionary. However, let us interpret some parts of it for you:
A - Alaafia fun o.
B - Buburu kan ki yoo subu lu o.
D - Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l'ori.
E - Ebi o ni pa o l'odun titun
E - Ekun, ose ko ni je tire.
F - Funfun aye re ko ni dibaje.
G - Gunnungun ki ku l'ewe, wa dagba d'arugbo.
GB - Gbogbo idawole re a y'ori si rere.
H - Hausa,Yoruba,Ibo,gbogbo eya ati eniyan kaakiri agbaye ni yo koju si o se o loore.
I - Iwaju, iwaju l'opa ebiti re yo ma re si.
J - Jijade re, wiwole re, o ni k'agbako.
K - Kukuru abi giga, osi ati ise ko ni je tire.
L - Loniloni wa r'aanu gba.
M - Monamona ati ara Olorun yoo tu awon ota re ka.
N - Naira, Euro, Dollar, Pound,Yen,Yuan,gbogbo owo ati oro kaakiri agbaye pelu omo alalubarika ati alaafia yoo mu o l'ore, won o si fi ile re se ibugbe.
O - Ojurere ati aanu yoo ma to o leyin ni ojo aye re gbogbo.
O - Ojo ola re a dara.
P - Panpe aye o ni mu o t'omotomo.
R - Rere ni agogo aye re o ma lu nigbagbogbo.
S - Suuru pelu itelorun ninu oro at'alaafia yoo ba o kale. S - Sugbon ati abawon aye re ti poora loni.
T - Tomotomo, t'ebitebi, t'iletile o ni d'ero eyin.
U - U ki s'awati lede Ijesha; a o ni fi o s'awati laarin awon eniyan. Ulosiwaju(ilosiwaju), userere(iserere), ati ubukun(ibunkun) yio je tire.
W -Wa ri ba ti se, wa r'ona gbe gba.
Y - Yara ibunkun, ire, ati ayo ailopin loo ma be e gbe titi ojo aye re......
AMIN ASHE EDUMARE.
Iwo naa fi ranse si awon eeyan re. __._,_.___
Ki ojo eni ko dara fun e tebi tara.
Ayo la o fi lo odun yi ja ni l'ase eduma
A-Good Health for you
B-no evil shall befall you
D-The troubles of sorrow will not fall upon you
E-You shall not go hungry this year
Complete all d rest jare
----------------------------------------------
KEEP UP WITH CBJ VIA ANY OF THESE:
CBJ PAGE: https://www.facebook.com/CentralBankofJokes
CBJ TWITTER HANDLE: @CenBankofJokes
CBJ BLOG: http://centralbankofjokes.blogspot.com/

No comments:
Post a Comment